ODUN N GORI ODUN
Bi odun ti n gori odun,
Lookan wa n wa loke
Ojo ti n rebi ana,
Orun ti n rebi atiwo!
Irin ajo alarin rin lo je,
Fun omo ati omo-omo,
Okan wa wa loke.
Bale ba ti n le,
A fi omo ayo fayo!
Ko ye ko digba ti o ba tan,
Ka to sonu,
Ka ma bu ola fun rawa loto.
Eniyan o sun won laaye,
Ojo aba ku laadere.
Ki waju le daara,
Ki eyin le sun won,
Oju aye eni laati mo bi yoo ti ri.
Oku n sunkun oku,
A kaso lori n sunkun ara won.
Bi e ti pe laye,
Ti e o tun fi aisan logba,
E dupe lowo Eledumare.
Eni koko re baye,
Oun lo mo lo.
Ko fi ifokan bale logba to ku,
Ki a ma gbadura lai sinmi.
Ki eleye ma ba siwaju eni lo ni.
Ojo ti n lo,
Ajo ipada sile sunmo.
Olorun je a wole ogo ni gba ti,
Ipe ti waba dun
5:30am
19th August, 2013
JA Okesiji ni eni odun marunleniogorin
(c)Olutayo IRAN-TIOLA, Lagos, Nigeria