Home / Tag Archives: Yoruba poetry (page 3)

Tag Archives: Yoruba poetry

Iran wa l’Obalende

Ile iwosan, Ile ijosin, Ile oni nabi, Bareeki orisirisi, Obalende. Ile gbigbe ni abi ti oja tita, To san toru ni aye n lo, Oko re losi gbogbo adugbo, Ona re si Idumota, Ona re si Ikoyi, Ibi o ba n lo ni o so, Obalende. E ro ra se, …

Read More »

AWA SOPE OLORUN IKOORE

Lati ibere pepe, Ni asiko ojo, Asiko Erun, Asiko otutu, Asiko Oru, Asiko gbigbin, Asiko ikoore! Olorun ninu ogbon re lo da won! Asiko ikoore, Ni mu ka ranti imisi Olorun, Olorun misi ile lakoko, O jade kuro ninu Ibu Omi, Olorun mi si ile, Eso orisirisi si jade wa, …

Read More »

ODIDERE TO RO!

E jeki a fi ti odidere to ro, Eye ti ki ku si oko iwa je, A mu lo, a mu bo, Ni owo n na enu! Odidere! Ka fi ti Odidere to ro, Ki a ma baa sirin, Ki a fi to Odidere to ro, Ka lo layo, ka …

Read More »

ASIKO

Mo wo rere, Mo wo otun, Mo wo osi, Mo bere pe kini asiko, Won wa dami lohun wipe: Asiko laye, Asiko laso, Asiko leniyan, Asiko laseyori, Asiko nigba, Asiko ni ti odere koko, Asiko ni fi eru joba, Asiko ni fi majesin joye, Asiko ni ru iwa, Asiko ni …

Read More »

MYSELF

I can’t be against myself, I stand to be myself, Whatever I do represents me, Can’t you catch me? Can you know my belly than me? I stand to defend all, And want to profit from all. (enu eni laa fí pe tèmi dire) The pride of my life, The …

Read More »

ADEDOYIN OLORUKO IYA!

Adedoyin Iya wa, If Grandpa called u Oloruko Iya, Who am I not to acknowledge you as Iya, You have some intent that show you as Iya, But you have some strong strength as Iya. Interestingly you are the last card. We were told of the first Adedoyin, She was …

Read More »

EWURE ILE O MO IYI ODE!

Ewure Ile o mo iyi ode, Se ti ogun to ko sinu gbere ni? Abi ti ijakadi to n ba iwun ja? Se ti ina cambadi to gbe sori? Abi ti iye ojo to fi n rin ninu igbe? Ka ma ti so ibiti o je ahere re? E je …

Read More »

O LE KU/ YOU CANNOT DIE

O LE KU To ba sun ojo faaji siwaju, O le ku. To ba run ori si, to run ese si, O le ku. To ba foju si ona aseyori, To mo pe, oun gbogbo lo lojo, O le ku. Awon to ti lo, O ku, Won fi ipa se, …

Read More »

Responsive WordPress Theme Freetheme wordpress magazine responsive freetheme wordpress news responsive freeWORDPRESS PLUGIN PREMIUM FREEDownload theme freeDownload html5 theme free - HTML templates Free Top 100+ Premium WordPress Themes for 2017 Null24Món ngon chữa bệnhCây thuốc chữa bệnhNấm đông trùng hạ thảo