Home / Tag Archives: Yoruba poetry

Tag Archives: Yoruba poetry

YORÙBÁ LÁKỌ̀TUN: BIRTH OF CULTURAL RENAISSANCE

In a bid to revive Yoruba language in Lagos, Nigeria, Olútáyọ̀ Ìrántíọlá, a cultural and literary enthusiast, developed Yorùbá LákỌ̀tun, an event aimed at cultural and literary renaissance. The first edition took place at Ethnic Heritage Center, Ikoyi, Lagos over the weekend. The center is a language training hub for …

Read More »

IPADABO

(Lati inu owe: Teni begi loju)Igi aruwedandan ni, Igi le ge, E o fa tu. Ti e o ba ti tu iru, Emi opin, Ise o tan, Eyi te se o soro,Ese meji loseyin!A si fi meji tesiwaju. A se ni se ara re,Oro pe emi loun se,Oun a fi ori se lotojo,Oun a fi ipa …

Read More »

OREKELEWA

Orekelewa, Eniti o ri ewa loye, Mo ri orekelewa to wumi, Lati ijo ti alaye ti daye, Ewa wa loju eniti o n wo, Ewa ti e koja oju, Ewa re de nu, Ewa re mu ife wa si okan mi, Ewa re lo je ki n moyii re,Mo mo yii oun ti mo ni,Maa si paa mo,Mo …

Read More »

GOLD CUM MIRROR

Precious metal, Sought with the heart, Possessed protectively, God bestowed everyone with it, Be grateful for your gold! Some have crude gold Some have refined gold, All that glitters ain’t gold But not like a mother. It’s not revered, Copious examples from the mirror, Thinking of your errors; see the …

Read More »

OYE LAYE

(Lati inu owe: Eniyan laso mi) Bi eni ba mooru, T o si aya si, Ma gbagbe pe: Oye laye. Bi asiko oginitin bade, O nilo nkan to fi bora, Ma gbagbe pe: Oye laye. Bi o ba dun loni, O le yi biri lola, Ma gbagbe pe: Oye laye. …

Read More »

MURA SI OUNJE RE!

Mura si ounje re, Ore mi, Ounje lafi n deni titobi, Bi a o ba reni fi jo, A tera mojije ni, Iya re le ma leran ni tan, Baba re le ma leran leti, Ohun to to ni mo wi fun o! O le ma lo ile iwe tan …

Read More »

Ki n ko po!

Ile mi ki se Eko, Oode mi ki se ihahin, Gbogbo atamo atamo yii, Ko ba mi lara mu to!E fimi sile bi mo tiri! Ikoko a mu omi tutu to fun mi, Isaasun olobe adidun temi lorun, Ko pa Baba Alaso, Ko pa Atanda, Yoo se wa pami? E …

Read More »

OLUSOSUN

Iru osun wo ni ka peyii? Won mu e lo si eyin odi latijo, O ti di aarin ilu wa yii, A fi oorun tun ilu se. Ogbooro lawon ti n sise lodo re, Ogbooro nibu kun o lojumo, Ogbooro ni ru eru wa fun o, Ogbooro lo n je …

Read More »

ORO NIYE (I)

WORDS ARE WORTHY (I) Words are my freedomFrom day to dayWords are my wanted friendsWords make my day Words are my freedomFrom day to dayWhether amidst a thousand fiendsI am bold to say A word banishes boredomAs darkness by a rayWords are a beauty when in trendsDispelling gloom and fray …

Read More »

Responsive WordPress Theme Freetheme wordpress magazine responsive freetheme wordpress news responsive freeWORDPRESS PLUGIN PREMIUM FREEDownload theme freeDownload html5 theme free - HTML templates Free Top 100+ Premium WordPress Themes for 2017 Null24Món ngon chữa bệnhCây thuốc chữa bệnhNấm đông trùng hạ thảo