OREKELEWA

Orekelewa, 
Eniti o ri ewa loye, 
Mo ri orekelewa to wumi, 
Lati ijo ti alaye ti daye, 
Ewa wa loju eniti o n wo, 
Ewa ti e koja oju, 
Ewa re de nu, 
Ewa re mu ife wa si okan mi, 
Ewa re lo je ki n moyii re,
Mo mo yii oun ti mo ni,
Maa si paa mo,
Mo mo iyi re,
Ma si sike re,
E ba mi pe orekelewa mi,
Elerin ti n fani mora,
A mu ori mi wo wu
ni igba gbogbo,
Iwo nikan lorekelewa
amu yan gan!

(c)Olutayo IRAN-TIOLA, Lagos, Nigeria
No Comments Yet

Leave a Reply

Your email address will not be published.