Ki n ko po!

Ile mi ki se Eko,
Oode mi ki se ihahin,
Gbogbo atamo atamo yii,
Ko ba mi lara mu to!E fimi sile bi mo tiri!
Ikoko a mu omi tutu to fun mi,
Isaasun olobe adidun temi lorun,
Ko pa Baba Alaso,
Ko pa Atanda,
Yoo se wa pami?

E fi mi sile bi mo tiri!

Ayo wa ninu aso wa,
Ki waso bi olola,
Ki gbogbo eniyan o se sadankata mi,
E bami se loso to daara!
E je n jo bata,
Ki gbogbo ara mi o na toto,
Bi mo ti ri gele nuu!
Igbalode dun,
Amosa,
E fimi sile ki n ko po!
Omo Yoruba tokantokan ni mi!

10:50pm, 5th July, 2014.

(c)Olutayo IRAN-TIOLA, Lagos, Nigeria
No Comments Yet

Leave a Reply

Your email address will not be published.