(Lati inu owe: Teni begi loju)
Igi aruwe
dandan ni,
Igi le ge,
E o fa tu.
Ti e o ba ti tu iru,
Emi opin,
Ise o tan,
Eyi te se o soro,
Ese meji loseyin!
A si fi meji tesiwaju.
A se ni se ara re,
Oro pe emi loun se,
Oun a fi ori se lotojo,
Oun a fi ipa mu ni baje,
Tesiwaju, owo palaba re fe se gi!
O papa parada,
Owo laaje,
Igi aruwe,
Teni begi loju.
(c)Olutayo IRAN-TIOLA, Lagos, Nigeria