ASIKO

Mo wo rere,

Mo wo otun,
Mo wo osi,
Mo bere pe kini asiko,
Won wa dami lohun wipe:
Asiko laye,
Asiko laso,
Asiko leniyan,
Asiko laseyori,
Asiko nigba,
Asiko ni ti odere koko,
Asiko ni fi eru joba,
Asiko ni fi majesin joye,
Asiko ni ru iwa,
Asiko ni la fi n wa ninu igbe,
Asiko la fi n ja igboro,
Ki asiko wa ma koja wa,
Ki asiko wa san wa,
Ki asiko o ye wa,
Ki asiko ko gbere ko wa,
Ki asiko o fun wa loro,
Ki asiko o fun wa lola,
Ki asiko o fi ara de wa,
Ki asiko ma ni wa lara,
Ki asiko o gbe wa leke,
Ki won ma fi asiko ti wa toro,
Ki won fi asiko ti wa sakawe ire,
Asiko lana,
Asiko loni,
Asiko lola,
Asiko lo jo aiye wa.
9:12am,
11thOctober, 2012
(c)Olutayo IRAN-TIOLA, Lagos, Nigeria
No Comments Yet

Leave a Reply

Your email address will not be published.