Home / Creatives / Poetry / MURA SI OUNJE RE!

MURA SI OUNJE RE!

Mura si ounje re,
Ore mi,
Ounje lafi n deni titobi,
Bi a o ba reni fi jo,
A tera mojije ni,
Iya re le ma leran ni tan,
Baba re le ma leran leti,
Ohun to to ni mo wi fun o!
O le ma lo ile iwe tan gbe,
Debi ti wa ma je ewa ti pa,
Booba ti ri pe o ga,
Ya mura lati tobi!
Enu lara,
Ma gba kiyawo ma da se Madam,

Ki wo na to Baba ke!
(c)Olutayo IRAN-TIOLA, Lagos, Nigeria

About Peodavies_office

Check Also

ADANNA

Rarely touch the ground, Does not look into one’s face, Stays mute in all discourse, …

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *