Home / 2014 / July

Monthly Archives: July 2014

HOPED-JOYFUL REUNION

It more than black, It is showing bleak, The state of the girls, Who are kept in the gaol, Counting days in hundred, Lives marching in hundred, Soldiers dying in hundred, Money spent and sort in billions! We have risen, We keep rising, We have spoken, We keep speaking, Till …

Read More »

WON TI KOJE!

Won ti ko oro won je, Won o tun pe wa ni obo mo, Won o to be lati pe wa ni ijimere mo, A ti segun ede won, Lo di fa fun Wole omo Soyinka, A ti segun imo won, Lo di fa fun opolopo ojogbon awawo dudu Loke …

Read More »

Ki n ko po!

Ile mi ki se Eko, Oode mi ki se ihahin, Gbogbo atamo atamo yii, Ko ba mi lara mu to!E fimi sile bi mo tiri! Ikoko a mu omi tutu to fun mi, Isaasun olobe adidun temi lorun, Ko pa Baba Alaso, Ko pa Atanda, Yoo se wa pami? E …

Read More »