Home / 2013 / September

Monthly Archives: September 2013

KA MA SO WON NU, KA TO SONU!

Obi ati onwoni,Kama so won nu, ka to sonu.Iya ati Baba eni,Kama so won nu, ka to sonu.Aki mu yi wura boro,Kama so won nu, ka to sonu,Aki fi isura wa pamo,Kama so won nu, ka to sonu.Bi won n be e loni, be ra re,Kama so won nu, ka …

Read More »

Let Fire Spark (audio)

Hello Friends, In order to delight you. I hereby share a poem with you. Let Fire Spark Listen to it and let’s know your feel. Kind regards (c)Olutayo IRAN-TIOLA, Lagos, Nigeria

Read More »

WO INU ARA

A san wo’ nu araWa gegebi ofin aye: Abata sinu odo,Awon odo sinu okun Titi losi inu ilu,Eniyan si ibise Asiko sinu igbaAdugbo sinu itan Ohun sinu nkanEniyan sinu ohun Aale sinu osan,Orun sinu imole Ibomirin sinu oda,Isun omi sinu akojopo yanrin, Itutu ninini sinu idapara,Ikoore sinu gbingbin Ajorin sinu …

Read More »

IPADE ELERE-IDARAYA

IPADE ELERE-IDARAYA Awo n pe awo! Tilu tifon!Awon akopa n figa gbaga,Won n sare ninu ogba alawo eweko yii,Bi ebora elere ti n pora lati okankan,Won n korin. Won n wo won, mo n gbo ninu iyaleni miAwon omode ti n yin epo wara. A SPORTS MEETColours call on colours! …

Read More »

Don’t Underrate Me

DON’T UNDERRATE ME (translated from Lawuyi Ogunniran’s MA RO MI PIN) It is said, “what would okro do?” Nwon ni, “Kini ila o se?”Okro turned, it overmatured, Ila se bee, o ko,They said, “what would garden egg do?” Nwon ni, “Kini ikan o se?”Garden egg wore garment of blood, Ikan …

Read More »

EKO

…ilu odaju LAAROWon a ji loworu kutukutu,Won a daju wia,Won a mura giri,Won a mu irin ajo pon,Won a morile ibise:Oko ero le je ti awon ole idaji,Oko ara eni leje ounje olopa.Owuro lojo lotito,Ere tete lese,A mo sa!Ko so pe ijamba oko oniwaye,Ko so pe ka ma sepe,Ko so …

Read More »