Home / 2013 / August

Monthly Archives: August 2013

WURA OUN JIGI

Isura Pataki,Oun ti a n fi gbogbo okan wa,Ba tun nitan, a tun kaya wa soke,Eledumare lo fi jinki wa lookankan,Dupe fun wura ti o fi fun o!Wura elomiran ti di ewura,Wura elomiran n dan gbinrin,Oun gbogbo to tun n dan ko ni wura,Bi ti Iya ko. A ki ka …

Read More »

Odun n gori odun

ODUN N GORI ODUN Bi odun ti n gori odun, Lookan wa n wa loke Ojo ti n rebi ana, Orun ti n rebi atiwo! Irin ajo alarin rin lo je, Fun omo ati omo-omo, Okan wa wa loke. Bale ba ti n le, A fi omo ayo fayo! Ko …

Read More »