Home / 2012 / August

Monthly Archives: August 2012

EWURE ILE O MO IYI ODE!

Ewure Ile o mo iyi ode, Se ti ogun to ko sinu gbere ni? Abi ti ijakadi to n ba iwun ja? Se ti ina cambadi to gbe sori? Abi ti iye ojo to fi n rin ninu igbe? Ka ma ti so ibiti o je ahere re? E je …

Read More »

O LE KU/ YOU CANNOT DIE

O LE KU To ba sun ojo faaji siwaju, O le ku. To ba run ori si, to run ese si, O le ku. To ba foju si ona aseyori, To mo pe, oun gbogbo lo lojo, O le ku. Awon to ti lo, O ku, Won fi ipa se, …

Read More »